Asájú
Sísọ síta
Ìtumọọ Asájú
The leader.
Àwọn àlàyé mìíràn
Also written as Aṣaájú. See: Aṣíwájú
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-ṣ(e-iw)ájú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whoṣe - make
iwájú - forward
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL