Asọdedẹ̀rọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Asọdedẹ̀rọ̀

The one who makes the town calm.



Àwọn àlàyé mìíràn

An appellation usually given to a king.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-sọ-òde-di-ẹ̀rọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - we, someone who
sọ - make
òde - town
di - become
ẹ̀rọ̀ - ease, softness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI