Asọ̀rọ̀dayọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Asọ̀rọ̀dayọ̀

One whose words (or issues) turn into joy.



Àwọn àlàyé mìíràn

Comes from the phrase an oríkì praising Ifá (deity of the Ifá oracle and divintion) and Ọ̀rúnmìlà, "Ifá olókun asọ̀rọ̀dayọ̀," meaning Ifá, the owner of the sea, one whose words turn into joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-sọ̀rọ̀-di-ayọ̀, a-sọ-ọ̀rọ̀-di-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
sọ̀rọ̀ - to talk
di - to become
ayọ̀ - joy
sọ - make
ọ̀rọ̀ - business, words, affair


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL