Arówómọlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Arówómọlé

1. One with enough money to know his home. 2. One with enough money to build a house.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-rí-owó-mọ-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
rí - see, find
owó - money
mọ̀ - know, recognise
ilé - house, home
-
a - one who
rí - see, find
owó - money
mọ - build, mould
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS