Arókodáre

Sísọ síta



Ìtumọọ Arókodáre

One who is happy to be on the farm.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-rí-oko-dá-àre



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
rí - see, find
oko - farming
dá - create
àre - goodness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL