Aródù

Sísọ síta



Ìtumọọ Aródù

We've seen the Ifá corpus.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-rí-odù



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - we, someone who
- see
odù - Ifá corpus/text; Ifá divination; message of Ifá


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO