Aróbíẹkẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Aróbíẹkẹ́

One who stands firm like the rafter.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ró-bí-ẹkẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
ró - stand firm, dúró
bí - like
ẹkẹ́ - rafter


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI
ILESHA
ONDO