Aríyùnkẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Aríyùnkẹ́

One cared for with iyùn (beads).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-rí-iyùn-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - someone
rí - see, find
iyùn - royal beads
kẹ́ - cherish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO