Aríyìmádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Aríyìmádé

One who finds great honour by wearing a crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-rí-iyì-mọ́-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
- see, find
iyì - value, worth, honour
mọ́ - add to
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OSUN



Irúurú

Aníyìmádé