Aríyáyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Aríyáyọ̀
One who rejoices at the sight of his/her mother.
Àwọn àlàyé mìíràn
The name is typically given to a child born into a family of many elderly women (parents, grandparents, etc). See also: Aríyehún
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-rí-ìyá-yọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whorí - find, see
ìyá - mother
yọ̀ - rejoice
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN