Aríwàjoyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Aríwàjoyè
One who brings a good character to this chieftaincy office.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-rí-ìwà-jẹ-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whorí - see, find
ìwà - character
jẹ - eat
oyè - honour
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Ọlọ́fà of Ọ̀ffà
Ọba Ọláwóore Ọlánipẹ̀kun Aríwàjòyè