Aríọláolúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Aríọláolúwa

We've seen the grace of God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-rí-ọlá-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - we, someone who
- see
ọlá - honour, grace, wealth, success, nobility
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL