Arébíṣọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Arébíṣọlá

One who makes success from family/good pedigree.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-rí-ebí-ṣe-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
- see, find
ebí - family (ẹbí)
ṣe - become
ọlá - wealth, success, notability, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE