Arówókọ́fá
Sísọ síta
Ìtumọọ Arówókọ́fá
Someone with enough money to learn Ifá
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-rí-owó-kọ́-ifá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one who; werí - to see, to find
owó - money, cowries
kọ́ - build, learn
ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IFE