Arógunmáyà
Sísọ síta
Ìtumọọ Arógunmáyà
He who sees the advancement of war but never steps aside.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Arógunmásàá.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-rí-ogun-má-yà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - someonerí - see, find
ogun - war, fighting
má - do not
yà - step aside
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL