Apálará

Sísọ síta



Ìtumọọ Apálará

The arms are one's closest kin.



Àwọn àlàyé mìíràn

The name comes from the saying "Apá l'ará, ìgùnpá n'ìyekan", meaning "the arms are one's kin and the shoulders are one's step siblings". It is a saying that comes from a popular Yorùbá poem encouraging hard work and self-sufficiency. See also: Iyelará, Ọmọlará



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

apá-ni-ará



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

apá - arms
ni - is
ará - kin, family, relation


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Lará