Anímáshaun

Sísọ síta



Ìtumọọ Anímáshaun

One who has and gives freely.



Àwọn àlàyé mìíràn

A variant of Anímaṣaun.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ní-má-se-ahun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
ní - have
má - don't
se - do
ahun - thriftiness, stinginess


Irúurú

Anímaṣaun