Anírèké
Sísọ síta
Ìtumọọ Anírèké
1. The owner of sugarcane. 2. We have sugarcane (aplenty).
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Onírèké
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-ní-ìrèké
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - someone, wení - have
ìrèké - sugarcane
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL