Anímáṣawun
Sísọ síta
Ìtumọọ Anímáṣawun
A generous giver.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Anímáṣaun, Anímáshawun, Anímáshaun
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-ní-má-ṣe-awun
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whoní - have
má - do not
ṣe - make, become
awun - a thrifty spender (also ahun)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL