Anífálẹ́yẹ
Sísọ síta
Ìtumọọ Anífálẹ́yẹ
One who has Ifá has honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-ní-ifá-ní-ẹ̀yẹ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one who; wení - to have, own
ifá - Ifá divination, priesthood, corpus
ẹ̀yẹ - honour, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI