Amúrawáyé

Sísọ síta



Ìtumọọ Amúrawáyé

One who is well-prepared for entering the world.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-múra-wá-ayé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
múra - be prepared, be well-dressed
wá - come, arrive
ayé - life, world, earth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Amúrawáiyé