Amúrawáíyé

Sísọ síta



Ìtumọọ Amúrawáíyé

One who is well prepared for entering the world.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-múra-wá-aiyé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
múra - be well prepared
wá - come, enter
aiyé - life, earth, world (ayé)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Amúrawáyé