Amọ̀nà

Sísọ síta



Ìtumọọ Amọ̀nà

The guardian. One who knows the way.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-mọ-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
mọ̀ - have knowledge of, be familiar with
ọ̀nà - way, road, path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL