Amúdípè

Sísọ síta



Ìtumọọ Amúdípè

A child of consolation.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-mú-dípẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who (is)
mú - take, use
dípẹ̀ - pay a debt, used for recompense


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE
IKARE