Alómájá

Sísọ síta



Ìtumọọ Alómájá

One who twists (something) but never snaps (it).



Àwọn àlàyé mìíràn

It's a praise-name, a cognomen.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-lọ́-má-já



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
lọ - twist
má - do not
já - break, snap


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IBADAN



Irúurú

Alọ́