Alókoláró

Sísọ síta



Ìtumọọ Alókoláró

One with big farms and enough resources to have others manage it for him.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ní-oko-ní-àáró



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
ní - have
oko - farm
ní - have
àáró - people paid to work on other people's farms


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Alókoláàró