Alárápé

Sísọ síta



Ìtumọọ Alárápé

The one with family is complete.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ní-ará-pé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
ní - have, own
ará - kin, family, relation
pé - complete


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL