Aládémọ̀mí
Sísọ síta
Ìtumọọ Aládémọ̀mí
Royalty knows me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
aládé-mọ̀-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
aládé - royal head, royalty, the owner of a crownmọ̀ - know
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Given name of the Deji of Akure Arakale (1768-1818)