Alánàmú

Sísọ síta



Ìtumọọ Alánàmú

One we have to stretch to catch.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is the title of one of the four Balóguns in Ìlọrin



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oní-à-nà-mú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oní - owner of
a - one who
nà - stretch
mú - pick, take


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Ibi tí a ti lè kà síi