Aládésanwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Aládésanwá

The royal one has rewarded us.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Aládésanmí



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

aládé-san-àwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

aládé - royal head, royalty, the owner of a crown
san - pay, benefit
àwa - us


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Aládésan