Aládékọmọ
Sísọ síta
Ìtumọọ Aládékọmọ
1. The paternity of the child is not in dispute. 2. Royalty does not reject children.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-ní-adé-è-kọ-ọmọ
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whoní - have
adé - crown
è - do not
kọ̀ - reject
ọmọ - child
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI