Alárapọ́n
Sísọ síta
Ìtumọọ Alárapọ́n
One with the fair skin.
Àwọn àlàyé mìíràn
A nickname.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oní-ara-pọ́n
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oní - one who owns; hasara - body, skin
pọ́n - fair skinned, red, ripe
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI