Aládodo
Sísọ síta
Ìtumọọ Aládodo
1. A rich person. 2. A tall person.
Àwọn àlàyé mìíràn
1. A nickname for someone who is very tall. 2. Adodo is a house built with arch entrance in Yoruba - Fulani villages in North Central part of Nigeria
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oní-adodo
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oní - the owner ofadodo - extreme tallness, a house built with an arch entrance
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL