Aládélúsì
Sísọ síta
Ìtumọọ Aládélúsì
The royal head has prestige.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
aládé-ní-ùsì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
aládé - royal head, royalty, the owner of a crownní - has
ùsì - fame, renown, prominence, honor, prestige, notability
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Déjì of Àkúrẹ́
Ọba Aládélúsì "Ọ̀dúndún Asọdedẹ̀rọ̀ I
" (1882-1890)
The current Déjì of Àkúrẹ́ Ọba Aládétóyìnbó Ògúnladé Aládélúsì
Ọ̀dúndún II
and surname of his descendants.