Aládéṣẹ̀yẹ

Sísọ síta



Ìtumọọ Aládéṣẹ̀yẹ

The owner of the crown has created honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

aládé-ṣe-ẹ̀yẹ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

aládé - royal head, royalty, the owner of a crown
ṣe - make
ẹ̀yẹ - honour


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adéṣẹ̀yẹ