Alábàjà

Sísọ síta



Ìtumọọ Alábàjà

One with àbàjà tribal marks on his/her cheek.



Àwọn àlàyé mìíràn

A cognomen, oríkì.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-ní-àbàjà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - someone
ní - have
àbàjà - the àbàjà tribal marks


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL