Akínyọ̀óyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínyọ̀óyè

Valor rejoices into chieftaincy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-yọ̀-(sí)-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
yọ̀ - rejoice
sí - into
oyè - honour, respect, chieftaincy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Akínyọ̀sóyè