Akínyọ̀ádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínyọ̀ádé

Valor rejoices into royalty.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-yọ̀-(sí)-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor
yọ̀ - rejoice
sí - into
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Akínyọ̀sádé