Akíntoríọlájúbàfólúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Akíntoríọlájúbàfólúwa

The brave one gives adoration to God for blessing him with wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-torí-ọlá-júbà-fún-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, the brave one
torí - because of
ọlá - wealth, success, notability
júbà - pay homage
fún - for, to
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA