Akínòsí

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínòsí

The valiant one is no more.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-ò-sí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor
- is not
sí - exist


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL