Akínlàlú

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínlàlú

The valorous one saved the town.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-là-ìlú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
- to survive, to save
ìlú - town


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL