Akínkúnlé

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínkúnlé

Valor fills the home; We have a lot of valiant ones at home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-kún-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, valiant one, bravery
kún - fill
ilé - home, house


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kúnlé