Akínjídé
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínjídé
The valiant one arrived early.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akín-jí-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave onejí - wake up, arise
dé - arrive, return
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IBADAN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Richard Akínjíde
Yoruba Nigerian lawyer and politician.