Akínfisóyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínfisóyè

Valor adds to honour.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Adéfisóyè, Ọláfisóyè.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-fi-sí-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, heroism, bravery
fi - adds, put
sí - into
oyè - honour, chieftaincy title


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Akínfióyè