Akínfọláyan

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínfọláyan

Valor struts with wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-fi-ọlá-yan



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery
fi - use
ọlá - wealth
yan - strut


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Fọláyan

Fọlá