Akíndọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Akíndọlá

Valor becomes honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-di-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
di - become
ọlá - honour, wealth, success, notability


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dọlá