Akínbàlóyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínbàlóyè

The valiant one (has) landed on the throne.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-bà-lé-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery
bà - land
lé - on top of
oyè - honour, chieftaincy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Bàlóyè