Akínbọ́dúnṣe
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínbọ́dúnṣe
The warrior came with the year (or festivities).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-bá-ọdún-ṣe
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave onebá - together with
ọdún - festivity, year, celebration
ṣe - make, create
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO