Akínṣòótọ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínṣòótọ́

The brave one tells the truth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-ṣe-òótọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
ṣe - make
òótọ́ - òtítọ́, truth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Akínshòótọ́