Akínṣíùn

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínṣíùn

The valorous one raised his voice.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-ṣí-ohùn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
ṣí - open, clear
ohùn - voice


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Akínṣíhùn